Jóòbù 37:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. “Ayà sì fò mi si èyí pẹ̀lú, ósì kúro ní ìpò rẹ̀.

2. Fetísílẹ̀! Fetísílẹ̀, kí ẹ sì gbọ́ ìróohùn rẹ̀, àti èyí tí ó ti ẹnu rẹ̀ jáde wá.

3. Ó ṣe ìlànà rẹ̀ ní ìsàlẹ̀ ọ̀run gbogbo,Mọ̀nàmọ́ná rẹ̀ ni ó sì jọ̀wọ́ rẹ̀ lọ́wọ́ dé òpin ilẹ̀ ayé.

Jóòbù 37