Jóòbù 37:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fetísílẹ̀! Fetísílẹ̀, kí ẹ sì gbọ́ ìróohùn rẹ̀, àti èyí tí ó ti ẹnu rẹ̀ jáde wá.

Jóòbù 37

Jóòbù 37:1-4