Jóòbù 3:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi kò wà ni ìléwu rí, bẹ́ẹ̀ ni èmi kò ní ìsinmi;bẹ́ẹ̀ ni èmi kò ni ìfàyà balẹ̀, síbẹ̀síbẹ̀ ìyọnu dé.”

Jóòbù 3

Jóòbù 3:17-26