Jóòbù 3:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí pé ohun náà tí mo bẹ̀rù gidigidi ni ó dé bá mi yìí,àti ohun tí mo fòyà rẹ̀ bá mi ó sì ṣubú lù mí.

Jóòbù 3

Jóòbù 3:19-26