Jóòbù 25:4-6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

4. Èé ha ti ṣe tí a ó fi dá ènìyàn láre lọ́dọ̀ Ọlọ́run?Tàbí ẹni tí a bí láti inú obìnrin wá yóò ha ṣe mọ́?

5. Kíyèsí i, òṣùpá kò sì lè í tànìmọ́lẹ̀, àní àwọn ìràwọ kò mọ́lẹ̀ ní ojú rẹ̀.

6. Áḿbọ̀torí ènìyàn tí iṣe ìdin, àtiọmọ ènìyàn tí iṣe kòkòrò!”

Jóòbù 25