Jóòbù 25:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èé ha ti ṣe tí a ó fi dá ènìyàn láre lọ́dọ̀ Ọlọ́run?Tàbí ẹni tí a bí láti inú obìnrin wá yóò ha ṣe mọ́?

Jóòbù 25

Jóòbù 25:1-6