Jóòbù 12:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun a mú orílẹ̀-èdè bí sí i, a sì run wọ́n;Òun a sọ orílẹ̀-èdè di ńlá, a sì tún ṣẹ̀ wọn kù.

Jóòbù 12

Jóòbù 12:22-25