Jóòbù 12:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó hú ìdí ohun ìjìnlẹ̀ jáde láti inú òkùnkùn wá,Ó sì mú òjìji ikú wá sínú ìmọ́lẹ̀.

Jóòbù 12

Jóòbù 12:21-25