Jóòbù 10:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ sá ti fi àwọ̀ ẹran ara wọ̀ mí,ìwọ sì fi egungun àti iṣan ṣọgbà yí mi ká.

Jóòbù 10

Jóòbù 10:10-12