Jóòbù 10:10-12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

10. Ìwọ kò ha ti tún mí dà jáde bí i wàrà,ìwọ kò sì múmí dípò bí i wàràǹkàsì?

11. Ìwọ sá ti fi àwọ̀ ẹran ara wọ̀ mí,ìwọ sì fi egungun àti iṣan ṣọgbà yí mi ká.

12. Ìwọ ti fún mi ní ẹ̀mí àti ojú rere,ìbẹ̀wò rẹ sì pa ọkàn mi mọ́.

Jóòbù 10