Jòhánù 18:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù dá a lóhùn pé, “Èmi ti sọ̀rọ̀ ní gbangba fún aráyé; nígbà gbogbo ni èmi ń kọ́ni nínú Sínágọ́gù, àti ní Tẹ́ḿpìlì níbi tí gbogbo àwọn Júù ń pé jọ sí: èmi kò sì sọ ohun kan ní ìkọ̀kọ̀.

Jòhánù 18

Jòhánù 18:12-23