Jòhánù 17:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi nínú wọn, àti ìwọ nínú mi, kí a lè ṣe wọ́n pé ní ọ̀kan; kí ayé kí ó lè mọ̀ pé, ìwọ ni ó rán mi, àti pé ìwọ sì fẹ́ràn wọn gẹ́gẹ́ bí ìwọ ti fẹ́ràn mi.

Jòhánù 17

Jòhánù 17:19-26