Jòhánù 17:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ògo tí ìwọ ti fi fún mi ni èmi sì ti fi fún wọn; kí wọn kí ó lè jẹ́ ọ̀kan, gẹ́gẹ́ bí àwa ti jẹ́ ọ̀kan;

Jòhánù 17

Jòhánù 17:12-26