Jòhánù 13:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Símónì Pétérù wí fún ún pé, “Olúwa, kì í ṣe ẹṣẹ̀ mi nìkan, ṣùgbọ́n àti ọwọ́ àti orí mi pẹ̀lú.”

Jòhánù 13

Jòhánù 13:1-19