Jòhánù 13:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù wí fún un pé, “Ẹni tí a wẹ̀ kò tún fẹ́ ju kí a san ẹṣẹ̀ rẹ̀, ṣùgbọ́n ó mọ́ níbi gbogbo: ẹ̀yin sì mọ́, ṣùgbọ́n kì í ṣe gbogbo yín.”

Jòhánù 13

Jòhánù 13:3-15