Jòhánù 13:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó dìde ní ìdí oúnjẹ alẹ́, ó sì fi agbádá rẹ̀ lélẹ̀ ní apákan; nígbà tí ó sì mú asọ ìnura, ó di ara rẹ̀ ní àmùrè.

Jòhánù 13

Jòhánù 13:1-14