Jòhánù 13:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tí Jésù sì ti mọ̀ pé Baba ti fi ohun gbogbo lé òun lọ́wọ́, àti pé lọ́dọ̀ Ọlọ́run ni òun ti wá, òun sì ń lọ sọ́dọ̀ Ọlọ́run;

Jòhánù 13

Jòhánù 13:1-10