Jòhánù 13:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kò sì sí ẹnìkan níbi tábìlì tí ó mọ ìdí tí ó ṣe sọ èyí fún un.

Jòhánù 13

Jòhánù 13:22-38