Jòhánù 13:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní kété tí Júdásì gba àkàrà náà ni Sátanì wọ inú rẹ̀ lọ.Nítorí náà Jésù wí fún un pé, “Ohun tí ìwọ ń se nì, yára ṣe é kánkán.”

Jòhánù 13

Jòhánù 13:21-33