Jòhánù 13:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Láti ìsinsìn yìí lọ ni mo wí fún un yín kí ó tó dé, pé nígbà tí ó bá dé, kí ẹ̀yin lè gbàgbọ́ pé èmi ni.

Jòhánù 13

Jòhánù 13:18-23