Jòhánù 13:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Kì í ṣe ti gbogbo yín ni mo ń sọ: èmi mọ àwọn tí mo yàn: ṣùgbọ́n kí ìwé-mímọ́ bá à lè ṣẹ, ‘Ẹni tí ń bá mi jẹun pọ̀ sì gbé gìgísẹ̀ rẹ̀ sí mi.’

Jòhánù 13

Jòhánù 13:14-23