Jòhánù 12:40 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ó ti fọ́ wọn lójú,Ó sì ti sé àyà wọn le;Kí wọn má baà fi ojú wọn rí,Kí wọn má ba à fi ọkàn wọn mọ̀,Kí wọn má baà yípadà, kí wọn má baà mú wọn láradá.”

Jòhánù 12

Jòhánù 12:37-46