Jòhánù 12:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nǹkan wọ̀nyí kò tètè yé àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀: ṣùgbọ́n nígbà tí a ṣe Jésù lógo, nígbà náà ni wọ́n rántí pé, a kọ̀wé ǹkan wọ̀nyí nípa rẹ̀ sí i.

Jòhánù 12

Jòhánù 12:11-19