Jòhánù 11:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Nítorí náà Tómásì, ẹni tí à ń pè ní Dídímù, wí fún àwọn ọmọ-ẹ̀yìn ẹgbẹ́ rẹ̀ pé, Ẹ jẹ́ kí àwa náà lọ, kí a lè bá a kú pẹ̀lú.”

Jòhánù 11

Jòhánù 11:6-17