Jòhánù 11:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi sì yọ̀ nítorí yín, tí èmi kò sí níbẹ̀, Kí ẹ le gbàgbọ́; ṣùgbọ́n ẹ jẹ́ kí a lọ sọ́dọ̀ rẹ̀.

Jòhánù 11

Jòhánù 11:11-20