Jòhánù 1:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun fúnrarẹ̀ kì í ṣe Ìmọ́lẹ̀ náà, ṣùgbọ́n a rán an wá láti ṣe ẹlẹ́rìí fún Ìmọlẹ̀ náà.

Jòhánù 1

Jòhánù 1:1-18