Jòhánù 1:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun ni a sì rán fún ẹ̀rí, kí ó lè ṣe ẹlẹ́rìí fún ìmọ́lẹ̀ náà, kí gbogbo ènìyàn kí ó lè gbàgbọ́ nípaṣẹ̀ rẹ̀.

Jòhánù 1

Jòhánù 1:1-14