Jòhánù 1:41 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ohun àkọ́kọ́ tí Ańdérù ṣe ni láti wá Símónì arákùnrin rẹ̀, ó sì wí fún un pé, “Àwa ti rí Mèṣáyà” (ẹni tí ṣe Kírísítì).

Jòhánù 1

Jòhánù 1:40-49