Jòhánù 1:40 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ańdérù, arákùnrin Símónì Pétérù, jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn méjì tí ó gbọ́ ọ̀rọ̀ Jòhánù, tí ó sì tọ Jésù lẹ́yìn.

Jòhánù 1

Jòhánù 1:31-42