Jóẹ́lì 3:14-16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

14. Ọ̀pọ̀lọpọ̀, ọ̀pọ̀lọpọ̀ní àfonífojì ìdájọ́,nítorí ọjọ Olúwa kù si dẹ̀dẹ̀ní àfonífojì ìdájọ́.

15. Oòrùn àti òṣùpá yóò ṣú òkùnkùn,àti àwọn ìràwọ̀ kí yóò tan ìmọ́lẹ̀ wọn mọ́.

16. Olúwa yóò sí ké ramúramú láti Ṣíónì wá,yóò sì fọ ohùn rẹ̀ jáde láti Jérúsálẹ́mù wá;àwọn ọ̀run àti ayé yóò sì mì tìtìṢùgbọ́n Olúwa yóò ṣe ààbò àwọn ènìyàn rẹ̀,àti agbára àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.

Jóẹ́lì 3