Jóẹ́lì 2:32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Yóò sí ṣe ẹnikẹ́ni tí ó ba ké pèorúkọ Olúwa ní a ó gbàlà:nítorí ní òkè Ṣíónì àti ní Jérúsálẹ́mùní ìgbàlà yóò gbé wà,bí Olúwa ti wí,àti nínú àwọnìyókù tí Olúwa yóò pè.

Jóẹ́lì 2

Jóẹ́lì 2:31-32