Jóẹ́lì 3:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ní ọjọ́ wọ̀n ọn nì, àti ní àkókò náà,nígbà tí èmi tún mú ìgbékùn Júdà àti Jérúsálẹ́mù padà bọ̀.

Jóẹ́lì 3

Jóẹ́lì 3:1-5