Ẹ fun ìpè ní Ṣíónì,ẹ sì fún ìpè ìdágàrì ní òkè mímọ́ mi.Jẹ́ kí àwọn ará ilẹ̀ náà wárìrì,nítorí tí ọjọ́ Olúwa ń bọ̀ wá,nítorí ó kù sí dẹ̀dẹ̀.