Jóẹ́lì 1:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó ti pa àjàrà mi run,ó sì ti ya ẹ̀ka igi ọ̀pọ̀tọ́ mi kúrò,ó ti bò èèpo rẹ̀ jálẹ̀, ó sì sọ ọ́ nù;àwọn ẹ̀ka rẹ̀ ni a sì sọ di fun-fun.

Jóẹ́lì 1

Jóẹ́lì 1:1-12