Nítorí orílẹ̀ èdè kan ti sígun sí ilẹ̀ mìírànó ní agbára púpọ̀, kò sì ní òǹkà;ó ní eyín kìnnìúnó sì ní èrìgì abo kìnnìún.