Jeremáyà 9:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n ti pèsè ahọ́n wọn sílẹ̀ bí ọfàláti fi pa irọ́; kì í ṣe nípa òótọ́ni wọ́n fi borí ní ilẹ̀ náà. Wọ́n ńlọ láti inú ẹ̀ṣẹ̀ kan sí òmíràn,wọn kò sì náání mi,ní Olúwa wí.

Jeremáyà 9

Jeremáyà 9:1-12