Jeremáyà 9:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Áà! èmi ìbá ní ilé àgbàwọ̀ fúnàwọn arìnrìn-àjò ní ihà kí nba à lè fi àwọn ènìyàn mi sílẹ̀kí n sì lọ kúrò lọ́dọ̀ wọn:nítorí gbogbo wọn jẹ́ pańṣágààjọ aláìsòótọ́ ènìyàn ni wọ́n.

Jeremáyà 9

Jeremáyà 9:1-11