Jeremáyà 8:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo ti fetí sílẹ̀ dáradára, wọnkò sọ ohun tí ó tọ́. Kò sí ẹnìkan tóronúpìwàdà nínú ìwà búburú rẹ̀,kí ó wí pé, “Kí ni mo ṣe?” Olúkúlùkùń tọ ọ̀nà rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ẹṣin tó ń lọ sójú ogun.

Jeremáyà 8

Jeremáyà 8:1-13