Jeremáyà 8:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

È é ṣe nígbà náà àwọn ènìyàn wọ̀nyífi yà kúrò lọ́nà rẹ̀? Kílódé tí Jérúsálẹ́mùfi yà kúrò ní gbogbo ìgbà?Wọ́n rọ̀ mọ́ ẹ̀tàn, wọ́n kọ̀ láti yípadà.

Jeremáyà 8

Jeremáyà 8:1-7