Jeremáyà 7:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyi ni ọ̀rọ̀ tí Olúwa àwọn ọmọ-ogun Ọlọ́run Ísírẹ́lì wí: Tún àwọn ọ̀nà yín ṣe, èmi yóò sì jẹ́ kí ẹ gbé ilẹ̀ yìí.

Jeremáyà 7

Jeremáyà 7:1-4