Jeremáyà 6:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èrè wo ni ó wà fún mi nínú tùràríláti ṣébà wá, tàbí eso dáradáraláti ilẹ̀ jínjìn réré? Ọrẹ sísun yínkò ṣe ìtẹ́wọ́gbà, ẹbọ yín kò sì wù mí.”

Jeremáyà 6

Jeremáyà 6:19-29