Gbọ́, ìwọ ayé! Mò ń múìparun bọ̀ sórí àwọn ènìyànwọ̀nyí, eṣo ìrò inú wọn, nítoríwọn kò fi etí sí ọ̀rọ̀ mi, wọ́n sìti kọ òfin mi sílẹ̀.