Jeremáyà 52:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ọ̀wọ̀n méjì agbada ńlá kan àti àwọn màlúù idẹ méjìlá tí ó wà lábẹ́ ìjókòó alágbèéká tí ó ṣe fún ibi pẹpẹ Olúwa, èyí tí ó kọjá èyí tí a lè gbéléwọ̀n.

Jeremáyà 52

Jeremáyà 52:13-22