Jeremáyà 52:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Balógun àwọn ìṣẹ́ náà kó àwokòtò, ohun ìfọná, ọpọ́n ìkòkò, ọ̀pá fìtílà, síbí àti ago wáìnì; èyí tí a fi wúrà àti fàdákà ṣe lọ.

Jeremáyà 52

Jeremáyà 52:9-25