Jeremáyà 52:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣédékáyà jẹ́ ọmọ ọdún mọ́kànlélógún nígbà tí ó jẹ Ọba. Ọdún mọ́kànlá ló fi jọba ní Jérúsálẹ́mù. Orúkọ ìyá rẹ̀ ni Hámútalì ọmọ Jeremáyà; láti Líbíná ló ti wá.

Jeremáyà 52

Jeremáyà 52:1-6