Jeremáyà 51:64 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ìwọ sì wí pé, ‘Báyìí ní Bábílónì yóò rì, kí yóò sì tún dìde kúrò nínú ibi tí èmi ó mú wá sórí rẹ̀: àárẹ̀ yóò sì mú wọn.’ ”Títí dé ìhín nií ọ̀rọ̀ Jeremáyà.

Jeremáyà 51

Jeremáyà 51:61-64