Jeremáyà 51:61 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jeremáyà sì sọ fún Séráíà pé, “nígbà tí ìwọ bá dé Bábílónì, kí ìwọ kí ó sì wò, kí ìwọ kí ó sì ka gbogbo ọ̀rọ̀ wọ̀nyí.

Jeremáyà 51

Jeremáyà 51:52-62