Jeremáyà 51:60 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jeremáyà sì kọ gbogbo ọ̀rọ̀ ibi tí yóò wá sórí Bébálì sínú ìwé kan, àní gbogbo ọ̀rọ wọ̀nyí tí a kọ sí Bábílónì.

Jeremáyà 51

Jeremáyà 51:53-63