Bí Bábílónì tilẹ̀ gòkè lọ sí ọ̀run,bí ó sì ṣe ìlú olodi ní òkè agbára rẹ,síbẹ̀ àwọn afiniṣèjẹ yóò ti ọ̀dọ̀ mi tọ̀ ọ́ wá,”ní Olúwa wí.