Jeremáyà 51:52 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Nítorí náà, wò ó, ọjọ́ ń bọ̀,” ni Olúwa wí,“tí èmi yóò se ìbẹ̀wò lórí àwọn ère fífin rẹ̀:àti àwọn tí ó gbọgbẹ́ yóò sì máa gbin já gbogbo ilẹ̀ rẹ̀

Jeremáyà 51

Jeremáyà 51:46-56